Iṣe Apo 16:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si là ẹkùn Frigia já, ati Galatia, ti a ti ọdọ Ẹmí Mimọ́ kọ̀ fun wọn lati sọ ọ̀rọ na ni Asia.

Iṣe Apo 16

Iṣe Apo 16:5-10