Iṣe Apo 16:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn oluwa rẹ̀ si ri pe, igbẹkẹle ère wọn pin, nwọn mu Paulu on Sila, nwọn si wọ́ wọn lọ si ọjà tọ̀ awọn ijoye lọ;

Iṣe Apo 16

Iṣe Apo 16:14-23