Iṣe Apo 16:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

On na li o ntọ̀ Paulu ati awa lẹhin, o si nkigbe, wipe, Awọn ọkunrin wọnyi ni iranṣẹ Ọlọrun Ọgá-ogo, ti nkede ọ̀na igbala fun nyin.

Iṣe Apo 16

Iṣe Apo 16:9-20