Iṣe Apo 15:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn kan ti ẹya awọn Farisi ti nwọn gbagbọ́ dide, nwọn nwipe, a ni lati kọ wọn ni ilà, ati lati paṣẹ fun wọn pe ki nwọn ki o mã pa ofin Mose mọ́.

Iṣe Apo 15

Iṣe Apo 15:3-12