Iṣe Apo 15:39-41 Yorùbá Bibeli (YCE)

39. Ìja na si pọ̀ tobẹ̃, ti nwọn yà ara wọn si meji: nigbati Barnaba si mu Marku, o ba ti ọkọ̀ lọ si Kipru;

40. Ṣugbọn Paulu yàn Sila, o si lọ, bi a ti fi i lé ore-ọfẹ Oluwa lọwọ lati ọdọ awọn arakunrin.

41. O si là Siria on Kilikia lọ, o nmu ijọ li ọkàn le.

Iṣe Apo 15