Iṣe Apo 15:33-35 Yorùbá Bibeli (YCE)

33. Nigbati nwọn si pẹ diẹ, awọn arakunrin jọwọ wọn lọwọ lọ li alafia si ọdọ awọn ti o ran wọn.

34. Ṣugbọn o wù Sila lati gbé ibẹ̀.

35. Paulu on Barnaba si duro diẹ ni Antioku, nwọn nkọ́ni, nwọn si nwasu ọ̀rọ Oluwa, ati awọn pipọ miran pẹlu wọn.

Iṣe Apo 15