Iṣe Apo 15:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina nigbati ijọ si sìn wọn de ọna, nwọn là Fenike on Samaria kọja, nwọn nròhin iyipada awọn Keferi: nwọn si fi ayọ̀ nla fun gbogbo awọn arakunrin.

Iṣe Apo 15

Iṣe Apo 15:1-4