Iṣe Apo 14:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọkunrin yi gbọ́ bi Paulu ti nsọ̀rọ: ẹni, nigbati o tẹjumọ́ ọ, ti o si ri pe, o ni igbagbọ́ fun imularada,

Iṣe Apo 14

Iṣe Apo 14:7-17