Iṣe Apo 14:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati lati ibẹ̀ lọ nwọn ba ti ọkọ̀ lọ si Antioku, lati ibiti a gbé ti fi wọn le õre-ọfẹ Ọlọrun lọwọ, fun iṣẹ ti nwọn ṣe pari.

Iṣe Apo 14

Iṣe Apo 14:17-28