Iṣe Apo 14:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si ti yàn awọn àgbagba fun olukuluku ijọ, ti nwọn si ti fi àwẹ gbadura, nwọn fi wọn le Oluwa lọwọ, ẹniti nwọn gbagbọ́.

Iṣe Apo 14

Iṣe Apo 14:17-26