Iṣe Apo 14:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn Ju kan si ti Antioku ati Ikonioni wá, nigbati nwọn yi awọn enia li ọkàn pada, nwọn si sọ Paulu li okuta, nwọn wọ́ ọ jade kuro ni ilu na, nwọn ṣebi o kú.

Iṣe Apo 14

Iṣe Apo 14:13-28