Iṣe Apo 14:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ko fi ara rẹ̀ silẹ li ailẹri, ni ti o nṣe rere, o nfun nyin ni òjo lati ọrun wá, ati akokò eso, o nfi onjẹ ati ayọ̀ kún ọkàn nyin.

Iṣe Apo 14

Iṣe Apo 14:10-27