Iṣe Apo 14:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Alufa Jupiteri ti ile oriṣa rẹ̀ wà niwaju ilu wọn, si mu malu ati màriwo wá si ẹnubode, on iba si rubọ pẹlu awọn enia.

Iṣe Apo 14

Iṣe Apo 14:5-18