Iṣe Apo 14:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn enia si ri ohun ti Paulu ṣe, nwọn gbé ohùn wọn soke li ède Likaonia, wipe, Awọn oriṣa sọkalẹ tọ̀ wa wá ni àwọ enia.

Iṣe Apo 14

Iṣe Apo 14:7-19