Iṣe Apo 14:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, ni Ikonioni, nwọn jumọ wọ̀ inu sinagogu awọn Ju lọ, nwọn si sọrọ tobẹ̃, ti ọ̀pọlọpọ awọn Ju ati awọn Hellene gbagbọ́.

Iṣe Apo 14

Iṣe Apo 14:1-9