Iṣe Apo 13:50 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn Ju rú awọn obinrin olufọkansin ati ọlọlá soke ati awọn àgba ilu na, nwọn si gbe inunibini dide si Paulu on Barnaba, nwọn si ṣí wọn kuro li àgbegbe wọn.

Iṣe Apo 13

Iṣe Apo 13:40-51