Iṣe Apo 13:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si wà ni Salami, nwọn nwasu ọ̀rọ Ọlọrun ni sinagogu awọn Ju: nwọn si ni Johanu pẹlu fun iranṣẹ wọn.

Iṣe Apo 13

Iṣe Apo 13:2-12