Iṣe Apo 13:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati niti pe o ji i dide kuro ninu oku, ẹniti kì yio tun pada si ibajẹ mọ́, o wi bayi pe, Emi ó fun nyin ni ore mimọ́ Dafidi, ti o daju.

Iṣe Apo 13

Iṣe Apo 13:29-36