Iṣe Apo 13:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi nwọn si ti mu nkan gbogbo ṣẹ ti a ti kọwe nitori rẹ̀, nwọn si sọ ọ kalẹ kuro lori igi, nwọn si tẹ́ ẹ si ibojì.

Iṣe Apo 13

Iṣe Apo 13:23-37