Iṣe Apo 13:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awọn ti ngbe Jerusalemu, ati awọn olori wọn, nitoriti nwọn kò mọ̀ ọ, ati ọ̀rọ awọn woli, ti a nkà li ọjọjọ isimi, kò yé wọn, nwọn mu u ṣẹ ni didajọ rẹ̀ lẹbi.

Iṣe Apo 13

Iṣe Apo 13:18-37