Iṣe Apo 13:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati lẹhinna ni nwọn bère ọba: Ọlọrun si fun wọn ni Saulu ọmọ Kiṣi, ọkunrin kan ninu ẹ̀ya Benjamini, fun ogoji ọdún.

Iṣe Apo 13

Iṣe Apo 13:12-23