Iṣe Apo 13:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ ti o kún fun arekereke gbogbo, ati fun iwà-ìka gbogbo, iwọ ọmọ Eṣu, iwọ ọta ododo gbogbo, iwọ kì yio ha dẹkun ati ma yi ọna titọ́ Oluwa po?

Iṣe Apo 13

Iṣe Apo 13:6-16