Iṣe Apo 12:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si mu u, o fi i sinu tubu, o fi i le ẹ̀ṣọ́ mẹrin awọn ọmọ-ogun lọwọ lati ma ṣọ ọ; o nrò lati mu u jade fun awọn enia wá lẹhin Irekọja.

Iṣe Apo 12

Iṣe Apo 12:2-7