Iṣe Apo 12:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si ti mọ̀ ohùn Peteru, kò ṣí ilẹkun fun ayọ̀, ṣugbọn o sure wọle, o si sọ pe, Peteru duro li ẹnu-ọ̀na.

Iṣe Apo 12

Iṣe Apo 12:10-22