Iṣe Apo 11:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi wà ni ilu Joppa, mo ngbadura: mo ri iran kan li ojuran, Ohun elo kan sọkalẹ bi gọgọwu nla, ti a ti igun mẹrẹrin sọ̀ ka ilẹ lati ọrun wá; o si wá titi de ọdọ mi:

Iṣe Apo 11

Iṣe Apo 11:1-6