Iṣe Apo 11:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina awọn ti a si tuka kiri niti inunibini ti o ṣẹ̀ niti Stefanu, nwọn rìn titi de Fenike, ati Kipru, ati Antioku, nwọn kò sọ ọ̀rọ na fun ẹnikan, bikoṣe fun kìki awọn Ju.

Iṣe Apo 11

Iṣe Apo 11:17-27