Iṣe Apo 11:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni mo ranti ọ̀rọ Oluwa, bi o ti wipe, Johanu fi omi baptisi nitõtọ; ṣugbọn a o fi Ẹmí Mimọ́ baptisi nyin.

Iṣe Apo 11

Iṣe Apo 11:6-24