Iṣe Apo 10:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni ijọ keji bi nwọn ti nlọ li ọ̀na àjo wọn, ti nwọn si sunmọ ilu na, Peteru gùn oke ile lọ igbadura niwọn wakati kẹfa ọjọ:

Iṣe Apo 10

Iṣe Apo 10:5-10