Iṣe Apo 10:41 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kì iṣe fun gbogbo enia, bikoṣe fun awọn ẹlẹri ti a ti ọwọ Ọlọrun yàn tẹlẹ, fun awa, ti a ba a jẹ, ti a si ba a mu lẹhin igbati o jinde kuro ninu okú.

Iṣe Apo 10

Iṣe Apo 10:34-46