Iṣe Apo 10:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ani Jesu ti Nasareti, bi Ọlọrun ti dà Ẹmi Mimọ́ ati agbara le e lori: ẹniti o nkiri ṣe ore, nṣe didá ara gbogbo awọn ti Èṣu si npọn loju; nitori Ọlọrun wà pẹlu rẹ̀.

Iṣe Apo 10

Iṣe Apo 10:37-45