Iṣe Apo 10:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Peteru si yà ẹnu rẹ̀, o si wipe, Nitõtọ mo woye pe, Ọlọrun kì iṣe ojuṣaju enia:

Iṣe Apo 10

Iṣe Apo 10:31-37