Iṣe Apo 10:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ ranṣẹ lọ si Joppa, ki o si pè Simoni wá, ẹniti apele rẹ̀ jẹ Peteru; o wọ̀ ni ile Simoni alawọ leti okun: nigbati o ba de, yio sọ̀rọ fun ọ.

Iṣe Apo 10

Iṣe Apo 10:29-37