Iṣe Apo 10:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Korneliu si dahùn pe, Ni ijẹrin, mo nṣe adura wakati kẹsan ọjọ ni ile mi titi di akoko yi, si wo o, ọkunrin kan alaṣọ àla duro niwaju mi.

Iṣe Apo 10

Iṣe Apo 10:29-33