Iṣe Apo 10:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Peteru sọkalẹ tọ̀ awọn ọkunrin ti a rán si i lati ọdọ Korneliu wá; o ni, Wo o, emi li ẹniti ẹnyin nwá: ere idi rẹ̀ ti ẹ fi wá?

Iṣe Apo 10

Iṣe Apo 10:12-29