Iṣe Apo 10:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olufọkansìn, ati ẹniti o bẹ̀ru Ọlọrun tilétilé rẹ̀ gbogbo, ẹniti o nṣe itọrẹ-ãnu pipọ fun awọn enia, ti o si ngbadura sọdọ Ọlọrun nigbagbogbo.

Iṣe Apo 10

Iṣe Apo 10:1-11