Iṣe Apo 10:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi Peteru si ti nronu iran na, Ẹmí wi fun u pe, Wo o, awọn ọkunrin mẹta nwá ọ.

Iṣe Apo 10

Iṣe Apo 10:17-21