Iṣe Apo 10:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Peteru dahùn pe, Agbẹdọ, Oluwa; nitori emi kò jẹ ohun èwọ ati alaimọ́ kan ri.

Iṣe Apo 10

Iṣe Apo 10:13-16