Iṣe Apo 1:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ẹnyin ó gbà agbara, nigbati Ẹmí Mimọ́ ba bà le nyin: ẹ o si ma ṣe ẹlẹri mi ni Jerusalemu, ati ni gbogbo Judea, ati ni Samaria, ati titi de opin ilẹ aiye.

Iṣe Apo 1

Iṣe Apo 1:7-12