Iṣe Apo 1:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ẹniti o si farahàn fun lãye lẹhin ìjiya rẹ̀ nipa ẹ̀rí pupọ ti o daju, ẹniti a ri lọdọ wọn li ogoji ọjọ ti o nsọ ohun ti iṣe ti ijọba Ọlọrun:

Iṣe Apo 1

Iṣe Apo 1:1-11