Iṣe Apo 1:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̀rẹ lati igba baptismu Johanu wá, titi o fi di ọjọ na ti a gbé e lọ soke kuro lọdọ wa, o yẹ ki ọkan ninu awọn wọnyi ṣe ẹlẹri ajinde rẹ̀ pẹlu wa.

Iṣe Apo 1

Iṣe Apo 1:15-26