Iṣe Apo 1:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni ijọ wọnni ni Peteru si dide duro li awujọ awọn ọmọ-ẹhin (iye awọn enia gbogbo ninu ijọ jẹ ọgọfa,) o ni,

Iṣe Apo 1

Iṣe Apo 1:12-17