1. Tim 6:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

KI gbogbo awọn ti iṣe ẹrú labẹ ìrú mã ka awọn oluwa ti o ni wọn yẹ si ọla gbogbo, ki a má bã sọrọ-odi si orukọ Ọlọrun ati ẹkọ́ rẹ̀.

1. Tim 6

1. Tim 6:1-9