1. Tim 3:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ gẹgẹ li o yẹ fun awọn diakoni lati ni ìwa àgba, ki nwọn má jẹ ẹlẹnu meji, kì nwọn má fi ara wọn fun waini pupọ̀, ki nwọn má jẹ olojukokoro.

1. Tim 3

1. Tim 3:7-11