1. Tes 5:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ẹ máṣe jẹ ki a sùn, bi awọn iyoku ti nṣe; ṣugbọn ẹ jẹ ki a mã ṣọna ki a si mã wa ni airekọja.

1. Tes 5

1. Tes 5:4-7