1. Tes 5:25-28 Yorùbá Bibeli (YCE)

25. Ará, ẹ mã gbadura fun wa.

26. Ẹ fi ifẹnukonu mimọ́ kí gbogbo awọn ará.

27. Mo fi Oluwa mu nyin bura pe, ki a ka iwe yi fun gbogbo awọn ará.

28. Ki ore-ọfẹ Oluwa wa Jesu Kristi ki o wà pẹlu nyin. Amin.

1. Tes 5