24. Olododo li ẹniti o pè nyin, ti yio si ṣe e.
25. Ará, ẹ mã gbadura fun wa.
26. Ẹ fi ifẹnukonu mimọ́ kí gbogbo awọn ará.
27. Mo fi Oluwa mu nyin bura pe, ki a ka iwe yi fun gbogbo awọn ará.
28. Ki ore-ọfẹ Oluwa wa Jesu Kristi ki o wà pẹlu nyin. Amin.