1. Tes 5:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki Ọlọrun alafia tikararẹ̀ ki o sọ nyin di mimọ́ patapata; ki a si pa ẹmí ati ọkàn ati ara nyin mọ́ patapata li ailabukù ni ìgba wíwa Oluwa wa Jesu Kristi.

1. Tes 5

1. Tes 5:19-28