1. Tes 5:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹ si mã bu ọla fun wọn gidigidi ninu ifẹ nitori iṣẹ wọn. Ẹ si mã wà li alafia lãrin ara nyin.

1. Tes 5

1. Tes 5:3-19