1. Tes 4:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li a ó si gbà awa ti o wà lãye ti o si kù lẹhin soke pẹlu wọn sinu awọsanma, lati pade Oluwa li oju ọrun: bẹ̃li awa ó si ma wà titi lai lọdọ Oluwa.

1. Tes 4

1. Tes 4:12-18