1. Tes 4:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori eyiyi li awa nwi fun nyin nipa ọ̀rọ Oluwa, pe awa ti o wà lãye, ti a si kù lẹhin de atiwá Oluwa, bi o ti wu ki o ri kì yio ṣaju awọn ti o sùn.

1. Tes 4

1. Tes 4:6-18